Home / Art / ‎ITUMỌ Olowo

‎ITUMỌ Olowo

 

Alaye: Ọpọlọpọ eniyan ro pe gbogbo awọn ti o wa ni ipo nlanla bii: gomina, aarẹ, alaga kansu,…tabi awọn to n gun ọkọ nlanla tabi to n gbe’le nlanla nikan ni ‪#‎olowo‬ laimọ wipe ko ri bẹ rara.
‪#‎ITUMỌ‬: Itumọ olowo ni gbogbo eniyan ti asiri ẹ bo, to jẹ pe t’oba fẹ lo owo kan to n ri lo lasiko to yẹ ati asiko to fẹ.
‪#‎ẸKỌ‬: Ẹ ma jẹki a maa fi ọla awọn kan ta o mọ ibiti wọn ti r’owo wọn tọrọ mọ. Ni agbara Ọlọrun, asiri gbogbo wa koni tu, amin!!!

About Lolade

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Colourful Photos: The Olowo of Owo Kingdom

His Imperial Majesty, Alaiyeluwa Oba Ajibade Gbadegesin Ogunoye III, The Olowo of Owo and Paramount Ruler of Owo KingdomPicture: Igogo festival 2019 See more photos bellow