Home / Art / Àṣà Yorùbá / Bómbù Déru Bà Wón Ní Ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond Bank) Ní Ìlú Jos
Suicide bomber
Suicide bomber

Bómbù Déru Bà Wón Ní Ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond Bank) Ní Ìlú Jos

Bómbù déru bà wón ní ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond bank) ní ìlú Jos, Bí won se fura wípé wón ti wà okò kan gúnlè tí irinsé olóró Bómbù sì wà ní inú rè.  Gbogbo òsìsé ilé-ìfowópamó Diamond ti eka Katako, ní Jos, àti àwon olùgbé ti sí kúrò léyìn tí okò afurasí tí ohun ìjà olóró wà nínú rè wà gúnlè ní iwájú ilé-ìfowópamó náà.
Ilé-isé kan tí a mò sí JTown connect metro kójopò wípé wón ti wa okò náà gúnlè fún ojó kan àti òpò wákàtí séyìn tí enikéni kò sì wá fún un.
Olùgbé àti òsìsé ilé-ìfowópamó ti eka Katako tí èrù ti ń bà pariwo síta or àwon tí ó le gbógun ti Bómbù, won kò sì pé tí won fi dé ibè.
Àwon tí ó ń gbógun ti Bómbù dí ònà tí òpò ènìyàn ń gbà láti dáàbò bo ènìyàn pèlú okò tí ó ń kojá.
Léyìn ìgbà tí won ti se ìwáàdí àti àyèwò fínífíní, àwon olù gbógun ti Bómbù gbógun ti ohun olóró yìí tí ó sì túká yángáyángá. Wo àwòrán síi ní ìsàlè….

English Version
Continue after the page break

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Èmi ni mo ni é” Adesua Etomi ni ó sobéè fún Banky W nígbà tí ó pín àwòrán ìgbéyàwó won.

   Àrídájú ti wà báyìí wípé Adesua Etomi àti Banky W ti di tokotayà, gbajúgbajà òsèré bìnrin ni ó sèsè pín àwòrán won yí tí ó sì so irú ìfé tí ó ní fun, nse ni ó dàbí eni wípé won bí won fún ara won ni, won bí won láti níìfé ara won ni, nítorí náà ìfé tí won ti ní síra ti pòjù. Banky W tí ó pín àwòrán kan náà ti se ìlérí láti níìfé rè títí ...