Home / Art / Àṣà Yorùbá / Dayo Amusa ti pada senu ise
dayo amusa

Dayo Amusa ti pada senu ise

Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi won ti n dana fiimu tuntun.

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

O lápátí

Kò tirẹ̀ lápátíKò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ àti ẹbí àti ará wa nígbà kankan. Àsẹ