Home / Art / Àṣà Yorùbá / IROYIN OWURO ose yii ti jade ooo

IROYIN OWURO ose yii ti jade ooo

Iru iku wo lo pa Sikiru Ayinde Barry Wonder? Inu iwe Iroyin Owuro ose yii ni e o ti ri. E gbiyanju ke e bere lowo fendo yin. Ogorun naira pere ni.

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

sharia

Won ti se idajo Sharia fun alagbere obirin

Obirin yii ni won ti se idajo Sharia fun ni orileede Indonesia latari wi pe, gbogbo igba lo n tele okunrin kan eleyii ti kii se oko re. Awon kan tile tun jeri wi pe, oseese ki maanu naa ti maa “kerewa” arabirin naa ni koro eleyii to tako ofin orileede Indonesia. Olayemi Oniroyin tun rigbo wi pe, oko arabirin naa kii fi gbogbo igba gbele eleyii lo fun obirin naa ni anfaani lati ma tele ale re kiri igboro ...