Home / Art / Àṣà Yorùbá / Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì. 
oko

Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì. 

Lagos response unit LRU tí a mò sí ìgbìmò ìdálóhùn wá ònà láti gbé okò ńlá tí ó kó yoyo tí ó ta òkìtì látàrí àìmu bírèkì ní òpópónà ojúelégbà, lónà pápá  bóòsì dúró (Stadium bus/stop) kúrò.
LRU gbé okò náà kúrò lónà…
Wo òpò àwòrán sì…..

English version after the page break.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

Ota ìbon tí àwon olópàá àti àwon ìgárá olóshà n yìn mó ara won sè sì bá awa kèké kan ní ìpínlè River.

    Oní kèké kan ní PortHarcourt ni ó ti kú látàrí ota ìbon tí ó se sì ta ba nígbà tí àwon ìgárá olóshà àti olópàá n yin ìbon mó ara won. Òdókùnrin tí ó jé oní kèké yí tí ó wá láti ìpínlè Ebonyi ti kú ikú òjijì nígbà tí ìbon ta ba léyìn tí ó jeun tán ní ilé oúnje .