Home / Art / Àṣà Yorùbá / Tàgiiri
Tàgiiri

Tàgiiri

Tàgiiri ma yí nìsó
Ara rẹ lokùn 
Ara rẹ ní ajé gbe ńso

Gbogbo ara tàgiiri fín so ajé 
Mo wá se ìwúre lo ní wípé ire owó yoo ma wọlé wa wa oooo
Gbogbo iṣẹ́ tí abá se,owó rẹpẹtẹ ní a o ma rí ní èrè láṣẹ Olódùmarè 
Àsẹ

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

owe

E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?

Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu. E seun.