Home / Art / Àṣà Oòduà / Iwure Eyonu Awon Agba
iwure

Iwure Eyonu Awon Agba

Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro.

Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni.
Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi).
Jowo Baba ologo lola ,je ki gbogbo awon ti
o ko ile aiye le lowo kan ma Yonu si wa(mi).
Nitoripe:Olubinuyo loruko ti won pe baba alawo.
Osaworomoja loruko ti won pe Esu odara.
Osese aya’ba loruko ti won pe ajuni lo.
Onyo lo ni ki won ma Yonu si mi.
Ekuku lo ni gbogbo ohun ti n ba se (do),ti o ba ku die k’ato ,ko bami ku danu.
Nitori sese l’omode yo mo eiye ,sese.
Sese l’agbalagba yo mo eiye,sese.
Nje Edua je kii gbogbo awon ti won ni ile aiye ma Yonu si mi.
Ki emi le ma yin e ,laiye yi ati nigba gbogbo!!!!
Aseeeee.

Lilo:owurokutukutu lo ti dara ju lati ma pe.

Compiled by humble me.
Baba alawo Ile’lawa

About admin

One comment

  1. Ekale sir, I am a graduate and i have no job and things are not working for me. I have been told in many places that a woman is behind my setbacks. i can barely afford to buy food. please sir what can i do

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

aje

Iwure AJE

Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje pe le oa kin lOrisas Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo koo ti ni Aje dakun wa jo koo temi ki or ma kuro mud my Translation Continue after the page break