Home / Art / Àṣà Yorùbá (page 10)

Àṣà Yorùbá

Àṣà Yorùbá, Asa Ibile Yoruba,  Yoruba je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ogbe Rikusa ifa Divination

Iwure Ojo Eti

Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.) Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi atejishe ee se (Aseee) labee ...

Read More »
Babalawo Ifakayode Ajani

Ose tu’a

ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare ...

Read More »