Home / Art / Àṣà Oòduà (page 169)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

ORIKI ORILE IREMOGUN

Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ...

Read More »

Eyin eniyan mi e ba mi dahun ibeere miyi:

Bawo ni awon yoruba se nki awon wonyi: (1)Agbede. (2) Ondiri (3) Babalawo (4)Akope Ati Alaboyun

Read More »

Ti iya oko e ba se omo tie bayi kini wa so?

Read More »

Akuu dede asiko yii: Arakuriyii Lord lugard !

Arakuriyii ni. Lord lugard ohun loo so Nigeria papo. Ejowo se daada lose fun wa ni abi aida?

Read More »

Eyin Eniyan me, Iru Oruko wo loye fun Arakunrin yi

Read More »

Iru oruko wo la le fun eleyi

E bami fun Arakurin yi ni oruko!

Read More »

Kini kati pe eyi ooo

Read More »

Nje o le daruko ilu kan nile Yoruba to lewa to ilu eko ?

Read More »

Kini toko taya file gbe d’ojo ale

Kini toko taya file gbe d’ojo ale (1) Ife (2) Otito (3) Owo (4) Iro (5) Ibalopo

Read More »

O pari!!!

  -Ibanuje aye e pari loni -Ekun ose aye e pari loni -Ait’egbe aye e pari Lati eni lo -Iya e pari lati oni lo -Asedanu aye e pari lati oni lo -o tun r’arun owo mo lailai -O koni ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb