Home / Art / Àṣà Yorùbá (page 20)

Àṣà Yorùbá

Àṣà Yorùbá, Asa Ibile Yoruba,  Yoruba je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Oríkì Ẹ̀rìn Òsun

Ẹ̀rìn moje ọmọ saaja, Ọmọ eléwé ladogba òróró maro, Ẹ̀rìn wagunwagun Ewá w’Ẹ̀rìn logun eniti yíò wá Ẹ̀rìn logun kowa àpò ide kolowa ọfà, Bàbá kòníbon ajíperin nílé, karo ń lè mọ wọn lójú ogun ẹni Ẹ̀rìn mọ jẹ́ ta ...

Read More »
relationship

Ìfẹ́ láàárín ara wa

Ìfẹ́ láàrin ara wa Ìfẹ́ dára, Ìfẹ́ dùn bí a bá pàdé oní tí wá, Ìfẹ́ jẹ́ òhun tí ó má ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn, Yálà ọkùnrin sí obìnrin, Obìnrin sí ọkùnrin, Ìyá sí ọmọ, Bàbá sí ọmọ, Ọkọ ...

Read More »
kanye west version

Aṣọ wíwọ̀

Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ...

Read More »
ominira

‪#‎Òmìnira‬

  Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú wàhálà ...

Read More »