Home / Art / Àṣà Yorùbá (page 3)

Àṣà Yorùbá

Àṣà Yorùbá, Asa Ibile Yoruba,  Yoruba je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Purity Okojie se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún méfà (6) ní àná: Mercy Johnson se ayeye ojó náà lo.

Akoni àti ogbóntàrigì òsèré obìnrin, tí a mò sí Mercy Johnson Okojie, tí ó fé omo oba Odi Okojie tí ó sì bí omo méta, Okúnrin kan obìnrin méjì. Mercy Johnson ti se ayeye ojó ìbí fún àkóbí rè, orúko ...

Read More »

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé Miracle.

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé ...

Read More »

Okò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé Jayce Jeremi, ti dé sí ìlú èkó.

Okò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé Jayce Jeremi, ti dé sí ìlú èkó. Linda Ikeji ti pin sí orí èro ayélujára láti fi hàn wípé okò tí ...

Read More »

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys.

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys. Ògbóntarìgì tí ó tún jé gbajúgbajà òsèré tí gbogbo èèyàn mò sí Sola Sobowale, wo aso aláràbarà ...

Read More »

Gideon Okeke àti Chidera Udueze se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won

Òsèré okùnrin tí gbogbo èèyàn Gideon Okeke ti se ìgbéyàwó ìbílè tàbí ti àbáláyé rè pèlú òkín láwùjo gbogbo eye, è yun ún ìyàwó rè tí ó rewà, orúko ìyàwó rè náà a máa jé chidera. Eléyìí kíì se iró ...

Read More »
saraki

Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje fún ilé-ìgbìmò Asòfin ti egbé PDP.

Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje fún ilé-ìgbìmò Asòfin ti egbé PDP. Báyìí ni àwon èrò àti àwon ará ìlú se pariwo mó Ààre ilé-ìgbìmò Asòfin àti olùdíje ilé-ìgbìmò ...

Read More »

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí.

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí. Alàgbà kan ní ìjo Catholic se oríre wípé èmi rè sì wà láyé nípa tí ikú ti fo orí rè kojá nínu ìjàmbá okò tí ó ní. Gégé bí ìròyìn ...

Read More »

Owó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè láàmú.

Owó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè láàmú. Ogbóntarigì gbómogbómo àti àwon adigunjalè tí ó n da àwon èèyàn ati awon olùgbé ìpínlè Adamawa láàmú ni owó àwon agbófinró tí a ...

Read More »
Tonto dikeh

Tonto Dikeh sòrò nípa arákùnrin tí ó n bá àyànfé ìyàwó rè jà níbi ìpéjo àríyà ti Burna Boy.

Tonto Dikeh sòrò nípa arákùnrin tí ó n bá àyànfé ìyàwó rè jà níbi ìpéjo àríyà ti Burna Boy. Gbajúgbajà Òsèré obìnrin tí a mò sí Tonto Dikeh, ti pín èrò rè sí orí èro ayélujára látàrí fídíò tí won ...

Read More »

Biodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì.

Biodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì. Gbajúgbajà Òsèré bìrin náà tí ólúwa fún ní ewà àti ara tí ó wuyì , orúko rè a máa jé Biodun Okeowo, ìnagije rè a sì máa jé ...

Read More »