Home / Art / Àṣà Yorùbá (page 5)

Àṣà Yorùbá

Àṣà Yorùbá, Asa Ibile Yoruba,  Yoruba je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Babalawo Ifakayode Ajani

Ose tu’a

ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare ...

Read More »
yoruba

APINTANBI

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun Ku isimi opin ose eledumare koni jeki a fi eleyi se asemo o ase. Laaro yi mo fe so die nipa oro APINTANBI ti awon opuro ati ...

Read More »