Home / Art / Àṣà Yorùbá (page 90)

Àṣà Yorùbá

Àṣà Yorùbá, Asa Ibile Yoruba,  Yoruba je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ọ̀RỌ̀ ÌSÍTÍ

Húùm…ètò ìsèlú tiwa-ntiwa kò yẹkí ó mú ìjà wá bí ó bá se wípé l’òtítọ́ la n’ìfẹ́ ará ìlú l’ọ́kàn, k’ára ó leè dẹ t’ẹrú-t’ọmọ yàtọ̀ sí ìsèlú bí-o-ba-o-pá, bí-o-kò-báa-kó- bu- bùú-l’ẹ́sẹ̀, èyí tó wọ́pọ̀ l’órílẹ̀ èdè wa!!. Àwa ọmọ ...

Read More »

‎ITUMỌ Olowo

  Alaye: Ọpọlọpọ eniyan ro pe gbogbo awọn ti o wa ni ipo nlanla bii: gomina, aarẹ, alaga kansu,…tabi awọn to n gun ọkọ nlanla tabi to n gbe’le nlanla nikan ni ‪#‎olowo‬ laimọ wipe ko ri bẹ rara. ‪#‎ITUMỌ‬: Itumọ olowo ...

Read More »