Home / Art (page 124)

Art

iwure

Iwure Eyonu Awon Agba

Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro. Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni. Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi). Jowo Baba ologo lola ,je ki ...

Read More »

Aje olokun yo fiso sile gbogbo wa ooo

AJÉ Iwọ́nrín Olókun a bi ara á ‘le koko bí ọta, Òhun l’ó d’ifa fún orí Àpéré ọ̀nà ọmọ a t’Àkàrà ṣ’ọlà.. (Ajé brings prosperity. I wish all Ifa University members a prosperous Ifa year. )Aṣẹ.

Read More »