Home / Art (page 129)

Art

Àwon Agbófinró

Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. 

Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun míràn tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. Ní ìsàlè ni òrò tí agbenuso àwon Agbófinró ìpínlè Èkó, SP Dolapo Badmos so. “E jò ó tí enikéni bá fi káàdì ìpè ráńsé sí yín tí ...

Read More »
omokurin

Àwon ológun yín ìbon lu omokùnrin odún márùn-ún ní Kaduna nígbà tí won ń ké ìrora won ní rowérosè ..

Gégé bí omo oòduà rere se so, omokùnrin odún márùn-ún tí orúko rè ńjé Hussein Mustapha ni àwon ológun yin ìbon lu nígbà tí won ń ké ìrora (rally) ní Kaduna láti fi àmì sí Qusday ní àgbáyé láti gba ...

Read More »
toke

Àwòrán; Toke Makinwa  jáde ní àrà òtò ní orílè èdè South Africa láti pàdé SA OAP àti àwon t’ókun lórí àjò SA tí ó ń bò lónà. 

Toke Makinwa sèsè dé sí orílè èdè South Africa láìpé yí gégé bí ó se ń rìn káàkiri àgbáyé láti di gbajúgbajà ònkòwé.  Ìmúra rè yanilénu nígbà tí ó wo aso aláwò   pupa férééfé (pink Gert Johan) àti bàtà ...

Read More »
gomino

Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró. 

Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì).  Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde ...

Read More »

Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà. 

Ní àná, ìgbìmò tí ó ń darí ètò ìdìbò (INEC) gba àpò méfà tí ó kún fún ìbowólù àwon tí ó tó láti dìbò ní agbègbè Eokun ìwò oòrùn ní ilè Kogi, tí ó ń bèèrè fún ìrántí Dino Maleye ...

Read More »
loo

Ipò Burúkú Ti Ilé-ìwòsàn Ńlá Ní Warri Ní Ìjoba Ìpínlè  Delta Wà. 

Èyí ni ìròyìn ipò tí ilé-ìwòsàn ńlá wà ní warri ní ìjoba ìpínlè Delta wà lówólówó . Àwòrán na jé pínpín sí orí èro ayélujàra (facebook) English Version Continue after the page break

Read More »

Ilé Tí Won Ń Kó Lówó Wó Ní Ilorin. 

Èrù ti ń ba àwon òpòlopò ènìyàn bóyá àwon ènìyàn kú sí inú ilé tí won ń kó lówó ní òpópónà Stella, Tanke ,Ilorin ,ní ìjoba ìpínlè Kwara tí ó wó ní òsán yí. English version Continue after the page ...

Read More »
daran

Àwon fúlàní darandaran kolu àwon àgbè oníresì (Rice farmer) ní ìjoba ìpínlè Benue.

  –Tí ó sì dá àpá sí  won l’ára. Nígbà tí a wà lénu síse àtakò àláfíà sí ilé ìjoba Makurdi lóòní láti jé kí ìjoba gbárùkù láti jé kí won f’owó sí owó ntanràn jíjeko (Anti grazing bill) sínú ...

Read More »
kcee

Kcee tú àsírí pé òhun ni olórin àkókò ní ìròlé èdè Nàìjíríà tí ó kókó lo okò bògìnì tí a mò sí Rolls-Royce phantom nínú fídío Orin rè. 

Gbajúgbajà olórin,  Kcee o ní ìràwò márùn-ùn. Nínú Orin tí ó ti se jé kí á rí àsírí rè gégé bí àsáájú tí ó kókó lo okò bògìnì “Rolls-Royce   ní ilé-isé olórin ní orílè èdè Nàìjíríà. Òun ni ó ...

Read More »
obanikoro

Àwòrán Obanikoro àti Oluremi Tinubu àti àwon omo egbé APC tó kùn ní ìlú èkó.

Ní ìsàlè yìí ni àwòrán sineto Obanikoro àti sineto Oluremi Tinubu àti àwon tó kùn. Ní ìpàdé kejilélógún (22nd) ní ibi ìpàdé àwon sinetò ní agbègbè èkó …. English Version after the page break

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb