Home / Art (page 3)

Art

ajayi

Ika logberi won o gboju lila f’Alawo #EsuIsNotSatan

The ignorants are wicked, they don’t want Yoruba Spirituality to prosper. To buttress my point stated above, i would summarize my message (Oro isiti), delivered at our Temple, Indigene Faith of Africa(Ijo Orunmila Ato)Inc on the 29th December 2018 from ...

Read More »

Purity Okojie se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún méfà (6) ní àná: Mercy Johnson se ayeye ojó náà lo.

Akoni àti ogbóntàrigì òsèré obìnrin, tí a mò sí Mercy Johnson Okojie, tí ó fé omo oba Odi Okojie tí ó sì bí omo méta, Okúnrin kan obìnrin méjì. Mercy Johnson ti se ayeye ojó ìbí fún àkóbí rè, orúko ...

Read More »

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé Miracle.

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé ...

Read More »

Okò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé Jayce Jeremi, ti dé sí ìlú èkó.

Okò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé Jayce Jeremi, ti dé sí ìlú èkó. Linda Ikeji ti pin sí orí èro ayélujára láti fi hàn wípé okò tí ...

Read More »

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys.

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys. Ògbóntarìgì tí ó tún jé gbajúgbajà òsèré tí gbogbo èèyàn mò sí Sola Sobowale, wo aso aláràbarà ...

Read More »

Gideon Okeke àti Chidera Udueze se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won

Òsèré okùnrin tí gbogbo èèyàn Gideon Okeke ti se ìgbéyàwó ìbílè tàbí ti àbáláyé rè pèlú òkín láwùjo gbogbo eye, è yun ún ìyàwó rè tí ó rewà, orúko ìyàwó rè náà a máa jé chidera. Eléyìí kíì se iró ...

Read More »

Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje fún ilé-ìgbìmò Asòfin ti egbé PDP.

Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje fún ilé-ìgbìmò Asòfin ti egbé PDP. Báyìí ni àwon èrò àti àwon ará ìlú se pariwo mó Ààre ilé-ìgbìmò Asòfin àti olùdíje ilé-ìgbìmò ...

Read More »
esu

Is Esu really Satan? By Babalawo Familusi Awolola

It is alarming to note the level of misinformation that has befallen the Yoruba race in lieu of our inclination towards alien esoteric knowledge.

Read More »

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí.

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí. Alàgbà kan ní ìjo Catholic se oríre wípé èmi rè sì wà láyé nípa tí ikú ti fo orí rè kojá nínu ìjàmbá okò tí ó ní. Gégé bí ìròyìn ...

Read More »

Owó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè láàmú.

Owó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè láàmú. Ogbóntarigì gbómogbómo àti àwon adigunjalè tí ó n da àwon èèyàn ati awon olùgbé ìpínlè Adamawa láàmú ni owó àwon agbófinró tí a ...

Read More »