Home / Art / Àṣà Oòduà / Ori iya mi ooooo! Ukwu ore Yemi Alade ti da gobe sile o.
yemi

Ori iya mi ooooo! Ukwu ore Yemi Alade ti da gobe sile o.

Wahala ti bere si ni sele lori ayelukara bayii, eleyii si bere nikete ti Yemi Alade se afihan foto re pelu awon ore, eni to se apejuwe won gege awon ololufe orin re. Awon eniyan ko tile soro nipa Yemi Alade, “apoti aje” ti ore re gbe seyin gan-angan lo fa rigimo oun surutu bayii.

olayemioniroyin.com

Send Money To Nigeria Free

About admin