Home / Jobs in Nigeria / Education / A list of carefully prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 4,900)

A list of carefully prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 4,900)

Onka ede Yoruba 100 – 20,000

1 – Ookan

2 – Eeji

3 – Eeta

4 – Eerin

5 – Aarun

6 – Eefa

7 – Eeje

8 – Eejo

9 – Eesan

10 – Eewa

11 – Mokanla

12 – Eejila

13 – Eetala

14 – Eerinla

15 – Meedogun

16 – Merindinlogun

17 – Etadinlogun

18 – Mejidinlogun

19 – Okandinlogun

20 – Ogun

30 – Ogbon

40 – Ogoji (i.e. Ogun Meji = 2 Twenties)

50 – Aadota

60 – Ogota (i.e. Ogun Meta = 3 Twenties)

70 – Aadorin

80 – Ogorin (i.e. Ogun Merin = 4 Twenties)

90 – Aadorun

100 – Ogorun (i.e. Ogun Marun = 5 Twenties)

110 – Aadofa

120 – Ogofa (i.e. Ogun Mefa = 6 Twenties)

130 – Aadoje

140 – Ogoje (i.e. Ogun Meje = 7 Twenties)

150 – Aadojo

160 – Ogojo (i.e. Ogun Mejo = 8 Twenties)

E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow) –

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

A kú osù tuntun oo.

Owó✋lá fi n sisé owó Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n wòlú Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn kàn Tó re inú ìrókò lo ree múlé si Tó n polówó ajé tantantan. Ó ní Alájé eni kìí la, kínú ó bínii Ñjé kí là ñ jé lótù Ifè tájé fi n yale ëni? ...