Home / Art / Àṣà Yorùbá / Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki
iyawo

Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki

Idunnu obi ni ki omo o yan ko si yanju. Omo taa to, to si duro gbeko ni i pada di omo gidi lowo awon obi re. Eyi  ni a le pe ni itan Tiwalade Ayuba lowo baba re.

Ayo ohun idunnu nla lo je fun idile gbajugbaja olorin fuji, Adewale Ayuba, lojo Monde to koja yii, 28/12/15, nigba ti gbogbo won on sin omo won lo si ile oko pelu ariya to fakiki eleyii to sele ni agbegbe Lekki ni ilu Eko.

Aimoye awon eniyan jankanjakan, awon olola ati gbajumo ni won pejo sibi ariya naa. Lara won ni Gbenga Adeyinka, eni to dari ayeye naa, Sule Alao Malaika, olorin to dana ijo fun awon alejo ojo naa. Lara awon gbajumo ojo naa tun ni Queen Salawa Abeni, Laide Bakare, KSB, Dayo Adeneye, Lepa Shandy, Tayo Odueke ati bee bee lo.

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !

Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ