Home / Art / Àṣà Yorùbá / Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko
britani

Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko

Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ijamba lorisiirisii. Gege bi alaye to te Olayemi Oniroyin lowo, apa ariwa ilu UK ni ijamba naa ti wopo julo nibi ti won ti ro gbogbo olugbe agbegbe naa lati sa asala fun emi won bayii.

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !

Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ