Home / Art / Àṣà Oòduà / Wahala sele ni Los Angeles lojo Satide: Rihanna fi komu lasan korin
rihanna

Wahala sele ni Los Angeles lojo Satide: Rihanna fi komu lasan korin

Lojo Satide to koja yii ni CBS RADIO ranse pe Rihanna, ogbontarigi akorinbirin ile America. Ariya to waye ni Hollywood Bowl to wa ni Los Angeles ni won se lati fi se igbonlongo wi pe awon obirin le segun aisan jejere oyan (Breast Cancer). Igba ti Rihanna korin de awon aye kan, n se ni omobirin eni odun metadinlogun (27) naa boso danu, to si n fi komu nikan korin.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

martynov

Broken Arrow