Home / News From Nigeria / Breaking News / 256 Odù Ifá signatures !
ÈJÌÒGBÈ
ÈJÌÒGBÈ - © Ifa University/ Moyo Okediji

256 Odù Ifá signatures !

ÈJÌÒGBÈ

I will be posting the 256 Odù Ifá signatures over the next one year. ( Bookmark this page or save it as it will be updated everyday/week)
If members are so inclined, they are encouraged to add Ẹsẹ Ifá verses that accompany the Odu,

Oṛúnmìlà á gbè wá o.

Èrè àti Òrúnmìlà

Láláìní owó lọ́wọ́
Kí lẹ̀dá ì bá fi dáṣà?
Láláìsí àṣà gbogbo
Kí lẹ̀dá ì bá fowó se?
5. Abẹ́ ṣẹnu ṣékélé
Bẹ́ ẹ̀ ni abẹ ń kọ ni
Olóbèlèjé ò ṣèèjì pẹkùn
A dífá fún èrè
10. Ńjọ tí ti ń jẹlée lọ́jà lọjà
Níjọ́ tí ti ń kólée lọ́ba lọ́ba
Ó wá pinnu àti jẹlé Àgbọnnìrègún
Baba ẹléṣin ọlóyán
Wọ́n ní kí baba farabalẹ̀
15. Ẹbọ ni kó ṣe
Èrè délé Alárá
Ó kólé Alárá
Èrè délé Ajerò
20. Ó kólé Ajerò
Èrè délé Ọwáràngún Àgà
Ó jẹlé Ọwáràngún Àgà
Ìròhìn kàn bá Ọ̀rúnmìlá
Wípé Èrè ti dájọ́, ó ti móṣù
25.Láti wa je Ile oun Orunmila
Ǹjẹ́ báwo ni èrè ò ṣe ní wáá jẹ òun?
Ni Ọ̀rúnmìlà ńdá Ifáá sí

© Ifa University/ Moyo Okediji

 Ìká Méjì

 Ìká Méjì

Photo credit – Popoola Owomide Ifagbenusola

Batik on Paper
Odu ifa – Ika Meji
Artist Kazeem Agboola.

Ìká Méjì — By Popoola Owomide Ifagbenusola

Opélopé Èjìká tí ò j’ewù ó bó
Opélopé baba Ire tó bí’ní l’ómo
Nló D’ífá fún Oníkamògún
Afi Òsányìn se’win bo
Ìgbà tíń sunkún òhun ò n’íre
Ebo Wón ní kó wá se
Ógbébo níbè ó rúbo
Èyin ò gbón o
Èyin ò mò
Òsányìn l’àwá ńbo là n’ílé wa.

Translation
If not for the shoulder that doesn’t allow our cloth to fall off
All thanks to a good father that give birth to us
Theh Casted Ifá for Oníkamògún
He who feed Òsányìn all the time
He was crying for not having Ire
He was advised to offer Ebo
And he complied
You all are not wise
You all do not know
It’s Òsányìn that we feed on our house before we become wealthy.
Àború Àboyè ooo!!!
~Owó

 

ÌWÒRÌ MÉJÌ

ÌWÒRÌ MÉJÌ

ÌWÒRÌ MÉJÌ – © Ifa University/ Moyo Okediji

 

Ọ̀YẸ̀KÚ MÉJÌ

Ọ̀YẸ̀KÚ MÉJÌ

Ọ̀YẸ̀KÚ MÉJÌ – © Ifa University/ Moyo Okediji

 

 

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

16 Ofun Meji

Ifa: The 16 Odu Ifa & Their Meaning.

The meaning of the 16 Odu Ifa of the Ifa is based on 16 symbolic or allegorical parables contained in the 16 Core Chapters or Principles that form the basis of the Ifá, a system of divination of the Yoruba people of Nigeria. The Grand Priest of Ifa, the Babalawo or Iyanifas are the Priests and Priestesses of the Ifa Oracle that receive and decode the meaning of the Divine Messages contained in the Odu Ifa Parables that are transmitted ...