Home / Art / Àṣà Oòduà / Alao Akala, Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn ní won fi egbé alásìá tí a mò sí PDP sílè lo sí egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.

Alao Akala, Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn ní won fi egbé alásìá tí a mò sí PDP sílè lo sí egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.

Baba ìsàlé egbé APC tí a mò sí asíwájú Bola Ahmed Tinubu, Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí ògbéni Rauf Aregbesola, Gómìnà ìpínlè Ondo, tí a mò sí Rotimi Akeredolu ní ìlú Ibadan ti fi tòwòtòwò gba olóyè Alao Akala, òsèré Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn láti inú egbé PDP sí egbé APC.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete