Home / Art / Àṣà Yorùbá / Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani Aaron ti gba àmì èye gégé bíi omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.

Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani Aaron ti gba àmì èye gégé bíi omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.

,Chidimma Leilani Aaron, omo odún méèdógbòn láti ìpínlè Enugu ti tayo àwon métàdínlógún (17) tí won jo díje fún omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà ti odún yí. O di eni kejìlélógójì tí yóò gba àmì èye yí ó sì lo ilé pèlú mílìònù méta náírà.
Ameh Rose ni ó se ipò keta tí Dunu sì se ipò kejì.
Gégé bí iwé ìròyìn daily times se se agbáterù rè, àjòdún tí ó máa n wáyé ní odoodún yí wáyé ní ilé ìtura ní ìlú Eko tí a mò sí Eko hotel. Òpòlopò àwon gbajúgbajà ènìyàn ni ô sì lo fún ojú lóúnje níbè.
Àwon Adájó ibè náà ni Rita Dominic, Ruchard Mofe Damijo, Olisa Adibua, Leesi Peter Vigbooro, Konye Nwabogor, Fade Ogbunro àti béè béè lo.
Ebuka àti Kayla Oniwo ni ó sì se agbáterù rè.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Àbámẹ́ta

Ní Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa

Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní fí se wá tọmọ tọmọ tebí taráỌlọ́run kò ní jẹ́ ka dùbúlẹ̀ àìsàn tọmọ tọmọ Gbogbo àìsàn arawa Olódùmarè yoo wòwá sàn kí ọ̀sẹ̀ yí tó parí