Home / Art / Àṣà Yorùbá / Arákùnrin tí ó n se yahoo ni ó ti ya wèrè nígbá tí bàbá eè kú tán ní ìlú Benin.

Arákùnrin tí ó n se yahoo ni ó ti ya wèrè nígbá tí bàbá eè kú tán ní ìlú Benin.


Kàyéfì nlá ni ó jé nígbà tí Arákùnrin kan ya wèrè ní ìlú Benin ní ìpínlè Edo.
Gégé bí ìròyìn se so, òdókùnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé isé kí á máa fi èro gbáni ni ó n se tí a mò sí Yahoo ni ó n se.
Nígbá tí ó ya sòkòtò pénpé mó ara rè tí ó sì jókòó sí ilè’lè ní ìta gbangba, tí ó sì n jéwó àwon ìwà ìbàjé kan.
Ìsèlè náa selè ní Agbior park by Ohovbe junction ní ìlú náa tí ó sì fa òpò èrò tí àwon ará àdúgbò sì fi se yèyé wípé àwon mòó dáadáa.
Won fi èsùn kàn wípé ó ra okò tuntun fún bàbá rè kí ó tó di wípé ó kú, won so wípé ó n kà wípé òun ti fi òpò ènìyàn se ògùn owó.
Nibi fídíò ti a rí wò nse ni arákùnrin yí n pariwo “Daddy, Daddy” nígbà tí ó fi ara rè se èsí ní ìta gbangba tí àwon èyàn sì ni kí ó máa jèrè isé owó rè.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !

Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ