Home / Art / Àṣà Oòduà / Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.

Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.

Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní òtá tí ó pò jaburata, òun sì ní láti ba ségun won.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete