Don't Miss
Home / Art / Àṣà Yorùbá / Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom

Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom

Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom.
Bí ó tilè jé wípé won ti sún ìdìbò síwájú látàrí àwon ìsèlè àifójúrí kan tí àwon tí ó n se ètò ìdìbo se nígbà tí won se ìpàdé, nígbà tí a gbo àwon ìròyìn kan ní wákàtí péréte kí ìbò bèrè. A gbó wípé , okò tí ó n kó èròjà ìdìbò lo sí ìjoba ìbílè Obot Akara ní ìpínlè Akwa Ibom ní won dáné sun tí èèyàn méjì sì kú.
Àwon méjì ni won ti di olóògbé ní ìpínlè Akwa Ibom nígbà tí won dáné sun okò won, nínú okò yí àwon àgùnbánirò wà níbè tí won n tèlé won lo láti lo ràn wón lówó láti ka ìbò ní olúkúlùkù ibi tí won fi won sí.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

May 29 And June 12 Declared As Public Holidays

The minister of information, Alhaji Lai Mohammed has just finished addressing a press conference that was broadcast live by the NTA, Radio Nigeria and Voice of Nigeria. He said: 1) President Buhari will be sworn in on May 29th. 2) The inauguration will be a low key event. 3) All the foreign dignitaries that would have been invited to attend the inauguration will be invited to attend an event on June 12 (Democracy Day). 4) Both May 29 and June ...