Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán tí Annie Idibia yà tí ó tún yo ní àrà òtò nínú aso ìbílè tí ó wò tí ó sì se ara l’óge.

Àwòrán tí Annie Idibia yà tí ó tún yo ní àrà òtò nínú aso ìbílè tí ó wò tí ó sì se ara l’óge.

   Òsèré obìnrin orílè èdè Nàíjíríà tí ó tún jé ìyàwó 2baba tí ó jé olórin nlá, olorì Idibia dàbí egbin lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W àti Adesua ní ojó ìsinmi tí ó kojá.

Mo dàgbà tán èwe wù mí, nse ni ó dàbí eni wípé ó tún n kéré si.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete