Home / Art / Àṣà Yorùbá / Àwon òrìsà tí e kò mò (sùgbón tí ó ye kí á mò) {Some Orisa you probably don’t know (But you have to)}
orisa

Àwon òrìsà tí e kò mò (sùgbón tí ó ye kí á mò) {Some Orisa you probably don’t know (But you have to)}

   Òrìsà Bayani. 
Òrìsà alágbára yí ni òrìsà omodé tí a bí pèlú dàda . Ó dára kí a ma bo òrìsà yí kí á sì ma bèèrè fún ìdábòbò, kí á b’orí òtá àti gbogbo ire ilé ayé.
Gbogbo ènìyàn ni ó le bo òrìsà yí, ó ń bá orí rìn ìdí ni yí tí a fi máa ń bo ó ní ilé-orí.
    Òrìsà kórì 
Èyí ni òrìsà omi fún èwe; ó ń dá ààbò bo èwe nínú ewu ayé,  ikú òjijì pèlú jàmbá abbl. Ó tún dára fún àgbàlagbà kí a bo ó fún èmí gígùn, oríre àti ìdábòbò. Gbogbo abiyamo ló gbodò bo òrìsà kórì láti bèèrè fún ìdábòbò omo won. Ó ń bá egbé rìn a sì le bo ó nínú kòkò egbé òrun.
     Òrìsà olúbòbòtiribò Baba enu 
Èyí ni òrìsà enu; ó dára láti bo ó fún eni tí ó ń wá ìdábòbò lórí èsùn ,enu ní agbára ńlá; agbára láti fún je, s’òrò, to wò, Kì í se gbogbo agbára rè ló da; o tún le s’épè pèlú enu re, o le ní èsùn kí o sì se èèyàn. Ìdí àtakò rè é tí ó fi ye kí á bo òrìsà yí kí a si fún ohùn rere nìkan kí òrò tí yóò ma jáde l’énu wa  láì gba èsè àti èsùn láàyè.
Òrìsà olúbòbòtiribò Baba a gbodò ma bo ó pèlú ayeye, tí a bá sì ń bo ó ounce gbodò wà fún àwon ènìyàn láti je. Inú kòkò ni a ti ń bo olúbòbòtiribò Baba enu….
Continue after the page break for English Version
Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

orisa

Focus and Trust your guardian Orisa !

Focus on your intuition and inner voice. And trust that your guardian Orisa are leading you in the right direction. Get back to the road and keep going…. Ire O! #African Spirituality# #Guardian Orisa# #Orisa# #Yemoja# #Yoruba# #Isese# #Goddess# #Ase#   Iyalorisa Omitonade Ifawemimo