Home / Art / Àṣà Oòduà / Bàbá Sàlá òrun rere re o. Gbajúgbajà elérí orí ìtàgé, tí gbogbo èèyàn mò sí bàbá Sàlá ti gba òrun lo ní àná ojó kesàn-án osù kèwà odún tí a wà yí.

Bàbá Sàlá òrun rere re o. Gbajúgbajà elérí orí ìtàgé, tí gbogbo èèyàn mò sí bàbá Sàlá ti gba òrun lo ní àná ojó kesàn-án osù kèwà odún tí a wà yí.


Tí won bá ni èèyàn apanilérìn ni baba won kò paró rárá, nítorí àwon gangan ni oyè adérìn-ín-p’òsónú ye.
Moses Olaiya Adejuwon (M.O.N), lórúko baba súgbón bàbá Sala ti gba orúko lówó won. Àsé kò sí eni tí kò ní kú, baba adérìn-ín-p’òsónú náà se bí eré lo sí òrun, Aláwàdà lo bá àwon baba rè lórun.
Baba Sala ó dìgbà, ó di ojú àlá.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete