Home / Art / Àṣà Oòduà / Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.
davido

Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.

Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.  Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí kò torí owó, orò bàbá rè má sisé mó, tí ó je wípé takuntakun ni ó fí n sisé láti le di èèyàn ñlá àti èèyàn pàtàkì tí àlá rè sì ti wá sí ìmúse. Omo bàbá olówó ni gbogbo ayé mo Davido sí nítori omo ìdílé Adeleke láti Ede ni. Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè Nìjíríà báyìí.  Sé owo ló tún fé ni àbí kíni? sùgbón ìfé orílè èdè rè tí ó wà lókàn rè ní ó mu fé sin orílè èdè rè.

davido

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

davido

Davido Weds Chioma In “1 Milli” Music Video

Davido releases the official music video for his hit love track “1 Milli“, starring Chioma. Directed by DK (DirectorK).