Home / Art / Àṣà Oòduà / Ẹ̀rọ̀ pẹ̀sẹ̀ ni tì’gbín. (Snail is for calmness)

Ẹ̀rọ̀ pẹ̀sẹ̀ ni tì’gbín. (Snail is for calmness)

Ìgbín (Snail) is for calmness, bringing troubling to a halt, tranquility and peace after a turbulence. Ẹ̀rọ̀ pẹ̀sẹ̀ ni tì’gbín.

– Bi igbin basu afi eyin e ko ; snail is use to return evils to who evils is from

– “Igbin” just like what one corpus said: ohun tenu ri lenu je adifa fun igbin to ma jele tio ni ku, igbin jele igbin o ku mo,gbogbo wa la o jefa lao se aseyori, aboru aboye
Translation:”snail” acording to a corpus: what ever the mouth see the mouth will eat cast devine for snail that will eat the soil and will not die, the snail eat the soil and succed,we will all succed in life, aboru aboye.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Yoo’ba loma n sope Igbin koni da enu dele….

Yoo’ba loma n sope Igbin koni da enu dele koma jifa ile Ifa owo ifa omo Ifa Alafia Ifa Ire Gbogbo kio wole to emin ati Iwo wa ! Ase !