Home / Art / Àṣà Yorùbá / E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii

E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii

Eyin ara Abule, e ba ni se akiyesi aworan yii daadaa. Se kii se pe ogbeni yii fee yin ibon AK47 mo obinrin yii lapa ni? 😀

E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii, asiko wo ni isele yii waye?

Agbegbe wo si lo ti waye?

Kini awon ohun ti asa abalaye Yooba se lori isele to se okunfa aworan yii?

N je a ri apejuwe kankan se lori iha ti awon eeyan ko si isele inu aworan yii?

E ku ikale….

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

ÌWÚRE ÒWÚRỌ̀

A kú ojúmọ́ o, a kú àsùnjí o, a sì kú ayọ́runbọ̀ di àlàyé ọkàn, àpayàn la máa pa òbí tiwa lónìí o, Ọlọ́run Elédùmarè a ṣe oore ọwọ́ ẹ̀ fún gbogbo wa bí ati ń jáde lọ síbi isẹ́ oòjọ́ wa lónìí. Mo gbàá ládùúrà lówurọ̀ yìí pé gbogbo ìdààmú àti wàálà ayé wa ni kí Ọlọ́run báwa fi òpin sí láti òní lọ, Ọ̀rúnmìlà ló sọ nínú odù IFÁ mímọ́ ẹ̀ pé, Àròyé awo Àgbìgbò lóṣe IFÁ fún ...