Home / Art / Àṣà Yorùbá / E ku Ose Ifa

E ku Ose Ifa

Aráká-Ajaga
Aràkà-Ajaga
Adifun Eniyan Ti Mú Iyè Meji Sin Èdú
Ènìyàn Ti O Sin Èdú,Ko Ma Se Iyè Meji
Aráká-Oku-Ajaga
Aràkà-Oku-Ajaga

🙏🏼Ase Tedumare🙏🏼

🐉Ifabukky Care🐲

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Photos from Ifa festival 2019 of Araba of Oworonsoki

Eni t’ase loore ti o dupe bi olosa ko ni leru loniAn ingrate is like a robber I wish to express my gratitude to everyone for the love shown on my Ifa festival 2019. My appreciation is expressed from my Odu of the year, “Irente gbe” as follows:- Ategbe ihin, Ategbe ohunAdifa fun Ireke ti ntorun bo waye Ebo adun ni won ni ko seO gbebo nbe o ruboOrunmila, OgiriyandaIfa wa fadun saye mi Ategbe here, Ategbe thereCast divination for sugarcane ...