Home / Art / Àṣà Oòduà / Eniyan koni rajo kofi orire kale sile ibiti aba koriwa mase pada leyinwa oo
ifa

Eniyan koni rajo kofi orire kale sile ibiti aba koriwa mase pada leyinwa oo

Ori mi Apere
isedami Ajifobi kan
Amuni wale aye magbagbe Eni
Orimi gbemi bose gbe omo alara tofidade owo
isedami gbemi bosegbe omo ajero tofi tepaleke
orimi gbemi bose gbe
omo orangun ila tofidi eni apesin pitipiti
mogbani Adurafun wape
oriwa Asegbe funwa o
ifa ni
sakasala legbe leke
Adifafun ori omo Amuwa gun boroboro
ebo lawoni komuse osi gbebobe orubo
eropo eroofa eyin omon
pe orilamuwa gun awo.

bi ori eni basunwan
wan ani ori enida
isedami jeki orimisunwan korimidi ori ola ati olaa ki mase se eru egbe mi oo
# Babalawo Ifatola Sangodare Awosipe

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

ifa

Truths of ìfá

Truths of ìfá