Home / Art / Àṣà Yorùbá / Èsì ìdánwò wo ló dára jù tí o ti gbà gégé bi akékòó ifáfitì tí kò tì parí ? 
idanwo

Èsì ìdánwò wo ló dára jù tí o ti gbà gégé bi akékòó ifáfitì tí kò tì parí ? 

Gégé bí akékòó tí kò ti parí ní ilé-ìwé gíga ifáfitì, àsìkò kan wà tí a ó rò wípé ayé ti ń se wá, àsìkò kan sì wà tí a ó rò wípé a ga ju ayé lo.

Ohun tí ó le fa àsìkò yí ni tí èsì ìdánwò bá jáde. A ti gbó nípa akékòó t’óbú gbàmù s’ékun tàbí se ohun tí ó burúkú jù béè lo, elòmíràn leè para rè látàrí èsì ìdánwò.
Sùgbón ní ibí a ó wo ìhà dáradára tí èèyàn bá rí èsì ìdánwò àwon isé tí ó dára tí ó se, tí ó sì ní pé. Béèni :mo darí ayé.

Níbí yìí à ó ma pín èsì ìdánwò wa tí ó dára jù tí a ti gbà gégé bi akékòó ifáfitì tí kò tì parí.

Láti jé kí á bèrè, èmi ma bèrè

Èsì ìdánwò mi tí ó dára jù nínú Engineering ni
Thermodynamics, (CHE201),97 A…..

Continue after the page break for English version

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

One comment

  1. Haha lobatan, ede yooba on pt… Ere itage 99A

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

Gómìnà Obina náà dìbò níbi ìdìbò Anambra.

Gómìnà Anambra Willie Obiano náà dìbò fún ara rè ní Otuocha ward 1 unit 004.