Home / Art / Àṣà Yorùbá / Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l) Ti Ilé-èkó Gíga Ifáfitì Tí Ó Wà Ní Ìpínlè Cross River
joy

Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l) Ti Ilé-èkó Gíga Ifáfitì Tí Ó Wà Ní Ìpínlè Cross River

Léyìn tí a gbó èsì ikú tí ó pa Joy Odama akékòó odún kejí (200l) ti ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó wà ní ìpínlè Cross river (university of science and technology (CRUTEC)) èyí tí ó kú ikú kàyééfi léyìn ìgbà tí ó rí Alhaji kan tí a mò sí Alhaji Usman Adamu ní ìlú Abuja ní osù kewàá odún tí ó Jojo.
       Gégé bí ìwé ìròyìn Vanguard, èsì ikú yìí tí ilé-ìwòsàn ìjoba àpapó (National hospital) ní ìlú Abuja gbé jáde , fihàn pé ikú májèlé ni arabìnrin náà kú, látàrí egbò igi olóró tí a mò sí kokeènì (cocaine). Agbó wípé arabìnrin yìí ní àìsàn okàn tí a mò sí (cardiogenic shock).  Ìyá olóògbé ,Philomena Odama, ní ìbèrè pèpè osù ti ko ìwé èbè (petition) sí ipò ààre  orílè èdè (presidency), ìgbìmò asòfin àgbà (Senate president), agbenuso ilé ìgbìmò asojú sòfin (speaker of house of representative), ògá àgbà ilé-isé olóòpá (IGP) DSS àti àwon èyà tí o ń dáàbò bo ìlú pèlú àwon tí ó wà ní ipò gíga nípa ikú omo rè. Nínú ìwé tí aya Philomena ko o se àfihàn bí eni tí won fura sí yìí ti máa ń gbé òpòlopò omoge ní èbá ònà tí ó sì máa ń se ìlérí wípé òhun o tó won ní iié-ìwé.
    Ní àkámó eni tí a fura sí yìí ní arabìnrin Joy odama kú sí. Ó sì ti gbìmò pò mó àwon olóòpá láti gbé omo náà sínú yìnyín láì fi tó àwon òbí rè létí. Àwon olóòpá ní kí àwon jáwó nínú ejó náà kí àwon sì gba egbèrún lónà egbèédógún (300,000) tí a fura sí yìí gbé fún won. Wípé àwon kò sì le è dá ejó nítorí gbajúmò tí ó túmò sí wípé òtòkùlú ni…….

English Version

Continue after the page break

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .

      Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra .    Àwon òré àti aféniféni ni won péjú p’ésè níbè láti fun ní ìbòwò ìkeyìn tí ó jé wípé àwon olùdábòbò sì n se ìwádìí ikú tí ó pa á….