Home / Art / Àṣà Yorùbá / Ẹ̀yẹ̀lé
eyele

Ẹ̀yẹ̀lé

Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, 
Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, 
Rirọ lonrọ àdábà lọrún, 
Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀, 
Tùtù ni omi àfi owúrọ̀ pònri, 
Ao ni mo inira layé ti àwá, 
Alanú kàn toju igba àlànú lọ, 
Yio wa wari, 
Mogbà làdúrà pe oké ti àwá ao ni jabọ, 
Ninu ọsẹ̀ yi ao ri owún tọkàsi ni rèrè, 
LAGBARA OLODÚMÀRÉ ỌBA TODA AYE TOFIFUN ỌRÚNMILA,

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !

Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ