Home / Art / Àṣà Yorùbá / Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task force) nígbà tí owó bà wón ní Benue.

Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task force) nígbà tí owó bà wón ní Benue.

Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am).

Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ìkan jé omo bíbí inú ìlú náà tí a mò pèlú ìnagije rè “Aníní “ti àwon méji tí ó kùn rè wá láti Vandeikya ní ìjoba ìbílè náà tí won yin ìbon pa wón nígbà tí won jo ń yin ìbon mó ra won pèlú àwon Joint Task Force.

Àwon adigunjalè yí ti wo ilé tí ó pò tí won sì gba owó àti èro ìbánisòrò won lo tí a sì ti gbà á padà lówó won, bákan náà ògá àwon adigunjalè yí bó tí a kò sì mo ibi tí ó wà

Continue after the page break for English Version

Send Money To Nigeria Free

About admin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

Odómokùnrin ilé-èkó girama ya Òrébìnrin rè lénu nípa èbùn ojó-ìbí tí ó fun tí ó sì fi gba ìfenukonu.

Àwòrán yí tí Òrékùnrin àti Òrébìnrin ilé-èkó girama ní bi tí won ti ń fi enu ko ara won lénu kárakára tí ó sì ti gbòde kan. Níbi àwòrán yìí arí àwon akékòó nísìírí sí omokùnrin náà bí ó se gbé èbùn ojó-ìbí náà fún olólùfé rè. Níbèrè Pèpè, ojú kókó ń ti omobìnrin náà sùgbón léyìn ìsírí tí àwon Òré rè fun, ó fa okùnrin náà móra ósì fi enu kò ó lénu.