Home / Art / Àṣà Yorùbá / Igi Agùnmáàníyè
Agùnmáàníyè

Igi Agùnmáàníyè

Agùnmáàníyè ni orúkọ igi yìí, a sì máa ń lo ewée rẹ̀ fi pa kòkòrò bíi ẹ̀fọn, ìdun àti ajẹlójú-ońlé. Pẹ̀lú èyí, a kò nílò oògùn ẹ̀fọn ìgbàlódé tí ó ń ṣe àkóbá fún ìlera ara wa tí à ń fín.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

ÌWÚRE ÒWÚRỌ̀

A kú ojúmọ́ o, a kú àsùnjí o, a sì kú ayọ́runbọ̀ di àlàyé ọkàn, àpayàn la máa pa òbí tiwa lónìí o, Ọlọ́run Elédùmarè a ṣe oore ọwọ́ ẹ̀ fún gbogbo wa bí ati ń jáde lọ síbi isẹ́ oòjọ́ wa lónìí. Mo gbàá ládùúrà lówurọ̀ yìí pé gbogbo ìdààmú àti wàálà ayé wa ni kí Ọlọ́run báwa fi òpin sí láti òní lọ, Ọ̀rúnmìlà ló sọ nínú odù IFÁ mímọ́ ẹ̀ pé, Àròyé awo Àgbìgbò lóṣe IFÁ fún ...