Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko pa
ijamba

Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko pa

Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko pa
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
Oro gbogbo kii se lori alabahun ni opopona Eko si Ibadan ati Ibadan si Eko. Lati igba ti awon Julius Berger ti bere ona naa ni titun se ni isolenu re ti po sii.


Ijeeje to o koja yii ni oko ajagbe eleru kan dede dubu ona ti moto kankan ko le wole bee si ni ko si eyi to le jade fun bii wakati mefa gbako.
Nnkan bii aago meje aabo ale oni naa ni ajagbe oko agbepo Kan tun gbana ti ko si oko to le koja lo Ibadan tabi wo Eko fun wakati kan gbako.


Opelope awon eso FRSC ati awon panapana ti won tete ji giri si oro naa.
Won bere si ni dari oko lati agbegbe ile epo Fagbems ti o je ibere Long bridge ti ko jinna lopo si ibi ti isele naa ti sele.
Eyo si mu ki gbogbo oko to n wo Eko ati eyi to n jade maa pin ona kan gba.
Ki Eledua so wa nibi ina leralera yii.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

fg

Àfàìmọ̀ Kí Coronavirus Má Dà Bí I Ti China Tabi Italy- Mínísítà Kìlọ̀

Ẹni mẹ́rin mì ìn kó àrùn apinni ní mímí èèmii coronavirus ní Nàìjíríà,àfàmọ̀ kò mọ́ dà bí i ti China,l Italy— Mínísítà kìlọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ìgbọrọ̀ sàn ju ẹbọ rúrú fún ẹni tó bá fẹ́ gbọ́ ni o.Ó ti di ogójì èèyàn tó ti lùgbàdì àrùn coronavirus báyìí lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lẹ́yìn tí àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ àrùn ní Nàìjíríà, NCDC kéde àwọn mẹ́rin míì tó ti ní àìsàn náà lálẹ́ ọjọ́ Ajé. Àjọ NCDC ṣàlàyé pé mẹ́ta nínú ...