Home / Art / Àṣà Oòduà / Ile itura alaja metalelogota (63) n jona bayii niluu Dubai
dubai

Ile itura alaja metalelogota (63) n jona bayii niluu Dubai

Bi a se n mura lati wo inu odun tuntun lo, ni aisun odun taa wayii, ile itura alaja metalelogota (63) kan an jona lo lowolowo bayii ni ilu Dubai eleyii ti won ko ti kapa ina naa. Bi a se n ko iroyin yii lowolowo, aja bi ogun ti jo kanle. Bakan naa ni ina naa n tesiwaju si i.



About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

dubai

The Dark Side of Dubai – The Dubai They Don’t Want You to See or Know