Home / Art / Àṣà Oòduà / Iṣẹ́ ìránṣẹ́ kò sí fún ìmẹ́lẹ́ èèyàn – Tunde Bakare
Tunde

Iṣẹ́ ìránṣẹ́ kò sí fún ìmẹ́lẹ́ èèyàn – Tunde Bakare

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ayé ló bàjẹ́ tí ọmọ olè ń dájọ; oníkálukú mọ ẹ̀tọ́ tó yẹ́’.
Olùṣọ́ àgùtàn Tunde Bakare ṣàlàyé bí ìdámẹ́wàá ṣe bẹ̀rẹ̀ ninu Bíbélì àti pé kò si ẹni tí wọ́n gbé ìbọn tì pé dandan ni kó san ìdámẹ́wàá.
Ó ní iṣẹ́ ọwọ́ òun ni òun ń jẹ nítorí pé Ọlọ́run kìí pe ọ̀lẹ sí iṣẹ́ àlùfáà.
Bakare sọrọ nípa ijọba Muhammadu Buhari pé ó ti gbìyanju, nítorí pé èèyàn ni èèyàn ó máa jẹ́ .
Ó ní àkókò tó fún Buhari láti lọ , kí ẹlòmíì le tẹ̀síwájú láti ibi tí Buhari bá iṣẹ́ dé.
Bákan náà ló mẹ́nuba àjọṣepọ̀ òun àti igbákejì Ààrẹ Ọṣinbajo pé, Ẹ̀gbá méjì kò gbọdọ̀ ja ara wọn níyàn,ni ọ̀rọ̀ àwọn.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Sowore

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti DasukiLati owoYinka AlabiIjoba apapo orileede Naijiria ni o ti ni ki Ogbeni Omoyele Sowore ti o je oludari “iroyin ayelujara Sahara” ati Sambo Dasuki ti o je oluba-Aare damoran pataki (NSA) nigba isejoba Goodluck Jonathan maa wa jejo lati ile ni osan oni ojo kerinlelogun, osu kejila odun 2019. Minisita eto idajo ni orileede yii, Abubakar Malami ni o gbe ejo naa kanri nigba ti ile ejo giga ti ni ki won maa wa ...