Home / Art / Àṣà Yorùbá / Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé Miracle.

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé Miracle.

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé Miracle.
Àwon olùgbé ìlú Sankwala jí ní òwúrò ojó kejìdínl’ógbòn osù òpe, odún 2018 láti rí òkú Miracle, tí ó jé omo bíbí Bayanung, Bassang, nígbà tí ó kúkú látàrí mímú wo egbé òkúnkùn.
Olóògbé yí kú látàrí gígé oríkè-ríkè ara rè.
Àwon mérin ni owó àwon olópàá Obanliku ti te, won sì ti kó won sowósí àwon agbófinró ní Diamond Hills ní ìpínlè Calabar, tí ó sì jé wípé Ajíhìnrere wà nínú won, nígbà tí ó sì je wípé omo ègbón rè ni won fé mú wo egbé láìmò.
Wàhálà àwon ará ìlú àti ègbón ajíhìnrere yí ti jásí pàbo nígbà tí àwon olópàá tí ó mú nílé ègbón rè ti sálo.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Yvonne-Rofem

Meet Yvonne Rofem, Self-acclaimed Tallest Girl In Nigeria.

Self-acclaimed tallest girl in Nigeria, Yvonne Rofem, a design, has been gaining plenty of attention in recent times. Students of the Federal University of Technology, Akure, Yvonee has been trending on social networking in recent months and there were a combined reactions on her behalf claim to function as the tallest girl in Nigeria. The feminine model standing at 6ft plus is definitely the cynosure of eyes everywhere she turns around and she is very a favorite figure on her ...