Home / Art / Àṣà Yorùbá / Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.
iresi

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway Restaurant &catering in Maryland US, ti se ipò kínní tí kò selè rí (jollof Hackathon) ti 1/0 se agbáterù rè níbi ayeye àjòdún ní Washington DC. Afropolitan insight ló se àgbékalè ètò náà.

Omidan Ogunsalu fi hàn fún gbogbo èèyàn wípé ní tòótó àwon ènìyàn Nàìjíríà le se ìresì àsèpò tí a mò sí jollof nígbà tí ó bá orílè èdè rè gbé igbáorókè. Àwon tí won jo figagbága ní orílè èdè Cameroon, Ghana àti Sierra Leone. Òkòòkan àwon tí ó wo ìpele tí ó kéyìn yí, ni a fún ní ìséjú márùn-ún márùn-ún Láti gbé ohun tí won ti se síwàjú, Adájó tí ejó won dà lórí I Akópa; ohun tí won fé se; tí tó wò àti bí ó se sè é.

Olùgbadé tuntun omidan Ogunsalu gba Dólà lónà egbèrún kan (US$1000) gégé bi olùbásisé pò láti owó olùbá-da-isé-pò 1/0 spaces àti àwon ànfààní láti di alásè ní jollof caviar African Fusion Restaurant èyí tí won sí ní Washington DC ní odún 2009…..

Continue after the page break for English version

Send Money To Nigeria Free

About admin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Gómìnà Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin

Gó́mìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin fún ìpamọ́ àti ìgbéga èdè Yorùbá

Aàrẹ Ọ̀nà Kakanfo, Ọ̀túnba Gàní Adams ti wọn ṣe ìwúyè fún ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, oṣù kini, ọjọ́ kẹtàlá ọdún Ẹgbàáléméjìdínlógún fi ẹ̀dùn ọkàn hàn nipa bi àṣà àti ìṣe Yoruba ti fẹ́ parẹ́.  Nigba ìwúyè, Ọ̀túnba Gàní Adams ṣe àlàyé pé́ ori ire ni wi pé kò si ogun ti ó nja ilẹ̀ Yoruba lọ́wọ́lọ́wọ́, ṣùgbọ́n òhun yio tẹra mọ́ṣẹ́ lati dáàbò àti bójútó àṣà àti ìṣe Yorùbá. Ìpínlẹ̀ Èkó ti tún ta wọ́n yọ lẹ́ ẹ̀kan si.  Ni Ọjọ́bọ̀, ...