Home / Art / Àṣà Yorùbá / ” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.

” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.

” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.

Ìròyìn tí ó gbòde kan láìpé ni wípé Tiwa Savage ti l’óyún tí Linda Ikeji so súgbón Tiwa Savage ti dékun ìròyìn rádaràda tí kò múná dóko yí. Ó mà ga o kí Elédùmarè gbàwá lówó àwon tí ó n só wa tí àwa kò só.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

A kú osù tuntun oo.

Owó✋lá fi n sisé owó Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n wòlú Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn kàn Tó re inú ìrókò lo ree múlé si Tó n polówó ajé tantantan. Ó ní Alájé eni kìí la, kínú ó bínii Ñjé kí là ñ jé lótù Ifè tájé fi n yale ëni? ...