Home / Art / Àṣà Yorùbá / Mr Harri se ìgbéyawó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar ní ìpínlè Eko.

Mr Harri se ìgbéyawó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar ní ìpínlè Eko.

Arákùnrin kan ní orílè èdè Nìjíríà ti ya òpò èyan lénu látàrí sése ìgbéyàwó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar rè. Tí e bá rò wípé e ti ri tán , eléyìí tún ya ni lénu ò.
Harri best ti pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí Insítágírámú láti pín àwòrán òun àti guitar rè tí won sì múra bíi toko taya, nígbà tí ó ko ìfé tí ó ní sì orin.
Ìsèlè yí selè ní ìpínlè Èkó, nígbà tí ó sì n ya èèyan ní enu wípé se iró ni àbí òtító.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !

Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ