Home / Art / Àṣà Yorùbá / Obara-Kanhin-Kanhin
iku

Obara-Kanhin-Kanhin

Bi-babalawo gbofa bi koba- gbo ifa , e je kafi obara kanhin kanhin looowo, Obara-kahin kanhin lo tutu toju enini lo,Obara kahin kahin awo ile Orunmila.

Awon losefa fun ORUNMILA(B.A).

Lojo ti IFA nbe laarin ota sangiliti,lojo ti EDU ALAJOGUN n sare lati gba iyi lawujo,o kesi awon AWO re,o ni kanye oun lowokan ibo wo,won ru won so, iyerosun kun oju opon teetete,won o rifa meji loju opon ayaafi OBARA-KANHIN-KANHIN,won ni ki BABA fokanbale wipe yio segun aiye,yio si fi eyin ota bele,yio tun gbayi kaari aaye titi dojo ale,won ni weere niyiosegun,weere sini ire gbogbo re yiode,won wa ni ti IFA bagba beeee,kolomarubo pelu(ewo-irorun,akikaragba,eyin-ibile mefa,agbo-onirooro-lorun,eyowo-ero 6,oko-arira kan,owo-ifa totawona.

Ewe odan,ewe ela 9,omunu akoko 21,efun,osun,aje olokun,aba owu,owu dudu ati funfun,abbl…) BABA gbebo nbe o rubo,o seun pupo,awa na rutiwa lojokini ana,kiwaju wa kodara ki eyin wa kosunhan lase awon tolaye,ebo BARA-APETU wa da ladaju,bi BABA se n se rere,lo n segun ota,o n reyin odi,o si tun n niyi kaakiri aiye…ise IFA ati igboran re dun looto ati lodoodo walahi,E JE KASE BIITI IFA,KI A LE LAYO DOJO ALE,A O GBUDO KO ETI IGBOIN SI EBO ATI IKILO IFA LAYEEWA,Ire nitiwa ooo.

Onifa yi komase biiti IFA nigba gbogbo,korubo isegun ati iyi,idile AAYAN lotiwa,kolobo OOSA AAYAN,kosi gbudo dijaa awon AWO re tobati looto,kodupe ona OKE-OYA ati OKE-OKUN,kodupe IFA,IYAAMI,OOSA AAYAN,ESU,OOOSANLA,SANGO OLUKOSO,abbl. Oro ifa siposiwaju nibe o.

Eni OJO AKOJO,mowaseni iwure wipe,ire AKOJO niyioje tiwa,a o ni rogun ETI mon laiyewa o,ao ri ojureere IFA lati gbayi lawujo o,a o sini bawon lo sode ibanuje laye,ogun OTA yio di asan lola IFA ODUEDE,eni eleni kosini jere ise tabase o.
IFA orimire ooo.
Ise IFA ntesiwaju.

-Fashola Omo Ogundakete.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

ooni ile ife

Google is the modern-day version of ‘Ifa’’ – Ooni of Ife.

The Ooni of Ife, Oba Enitan Ogunwusi, on Wednesday said that the Google originated from the ‘Ifa’ also known as the oracle. The traditional leader said that without ‘Ifa’, Google would not have been created. Ogunwusi said this during the press tour of the tourists sites within the ancient city ahead of the Tourism Innovation and Development Innovation Conference (TIDA) slated for April 24. The theme of the forthcoming conference is:” Impact of Sustainable Tourism Development and Marketing of Tourism ...