Home / Art / Àṣà Oòduà / Obi ni n bi arun
kolanut

Obi ni n bi arun

Aboru
Aboye
Abosise..
Ifa niiiiii

Obi ni n biku
Obi ni n bi arun
Obi ni n bi ofo
Obi ni n bi gbogbo ibi.
Olodumare abawa fi obi biku, bi arun, bi ofo, bi gbogbo ajogun ibi aye wa o.
Ase edumare.

Sponsored by Asa Oodua

Cola nut helps to avoid death
Cola nut helps to avoid disease
Cola nut helps to avoid lost
Cola nut helps to avoid all kind of problems.
I pray Olodumare will use Cola to take away all the problems in our life.
Ase edumare.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19

Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan bii ose meji to koja lo.Arun yii ko mu oun nikan, o tun mu mefa miiran ninu ebi re. Oni yii ni ori ko alagba naa yo pelu awon ebi re mefeefa.Oluulu Naijiria, Abuja ni won ti ģba iwosan tiwon, ni ibi ti won ...