Home / Art / Àṣà Yorùbá / Itunmo Ala wipe e ri obo loju orun
obo

Itunmo Ala wipe e ri obo loju orun

Bi o bala ala wipe loju orun wipe e ri awon obo (monkey) meji loju orun tiwon tele ara won alayi dara pupo olorun oba yio seo loore male gbagbe orore yio dayo ona owo yio la fune beesini bio baje eniti onwa iyawo waari ololufe eni bi okanre gidi beesini bio baje obinrin tion woju olorun oba ni ibeji omo nwae bowa ni kiakia iwo olorun oba oore idunnu mi fi lemi lowo ooamin

Ayandare Olasunkanmi Luqmon Ebedi > ALALILA PELU ITUMORE ATI ONA ABAYO LORIE whatssap or Calling 08089038658

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

iwure

Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..

Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ire tí kálukú wa bá kójọ kò ní pẹ̀dí mọ́ wa lọ́wọ́ o láṣẹ Olódùmarè. Àsẹ